Oladips – Escolopidium – (Funwonje) Lyrics

Oladips – Escolopidium – (Funwonje) Lyrics

Beat-Boi-Classik
The Dipsciples Music
Yah Yah
Yah!
(Ahan-Ahan)
Moti Kọ HipHop Moti Kọ Raggae
O’dayanmo? Ola Emi N Kọ Yéye
Bèrè Mi L’ọ́wọ́ Àwọn Toti N Gbọ Tey-Tey
Atawon Morufa Ìdí Gan Lébè
Bi Moṣe N Funwon Lo N Pariwo Chineke

Fa Ìlù Ya Funwon Bi Sunny-Nweke
Òròmọ Adìyẹ, Àsá Súré Gbe
Environmental Awa N Tun Ilé Ṣe
Èmi Ni Alágbe Ẹyin Ní Elégbè
Èmi Ni Al’adura Ẹyin Ní Elépè
Èyí Tatun Gbede, Otun Peléke
Awon Olórin Wẹwẹ̀wẹ́ Wonti F’erége
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyún Towa Nínú Habiba?

Wo? Brother You Fit Ask Ifá
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyún Towa Nínú Habiba?
Wo? Brother You Fit Ask Ifá
Anytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Kú’lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Jọ)
Dem Go Want Make I Do More

Yah! Yah!! Yah!!!
Anytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Kú’lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Ṣẹ)
Dem Go Say Make I Do More
Ya! Yah!! Yah!!!
Ọlá Fúnwajẹ Jọ
Fúnwajẹ Jọ, Fúnwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Fúnwọnjẹ Jọ,
Fúnwọnjẹ Jọ, Fúnwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Hmmm Sọpé Ótilọ)
Ọlá Fúnwajẹ Jọ

Fúnwajẹ Jọ, Fúnwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Fúnwọnjẹ Jọ,
Fúnwọnjẹ Jọ, Fúnwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Sọwípé Ótilọ)
My Music Be Like Person Wey Done Gbé Banku,
E Dey Carry Them Trabaye
Báwo Lóṣe Ń Ṣeyín Ẹ Ṣàlàyé
Ọmọ Tí Ẹti Fi Ojú Di Yẹn Màmàré
Moru Kpoun-Kpoun Gan Ki N Tó Di DON-GORGON

RELATED POST:   Olexesh – Durak Lyrics

Moti Fọ Abọ́ Gan, Motún Lo Ọwọ́ Kan
Ṣaléwá Break My Heart Modẹ̀ Fi Sí Ọkán
But Moti Ṣe Ọwọ́ Kan, Kí Wántó Fi Fún Ọkọ
Moní Gọngọ Sọ, Ní Ọmọ Tí N Sponsor?
Bi Ṣe Ń Tẹ R2 Lóse Ń Tẹ Cursor
Èmi Ọmọ Tí Wọ́n Ń Sọ, Tí Ótuń Tasánsán
Ọwọ́ Tí Ofi Fọ Ata, Má Fi Fọ Bumbum
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa
Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyún Towa Nínú Habiba?
Wo? Brother You Fit Ask Ifá
Ẹni Orí Yọ Ìyẹn Tijẹ Home Training Kpa

Talosope Whyning Òkínṣe Fipá?
Woni Talo Ní Oyún Towa Nínú Habiba?
Wo? Brother You Fit Ask Ifá
Anytime Wey I Pull Up
Wọ́n Ma Kú’lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Jọ)
Dem Go Want Make I Do More
Yah! Yah!! Yah!!!
Anytime Wey I Pull Up

Wọ́n Ma Kú’lọ
Óyá Sọpé Ótilọ
(Ótilọ Sẹ)
Dem Go Say Make I Do More
Ya! Yah!! Yah!!!
Ọlá Fúnwajẹ Jọ
Fúnwajẹ Jọ, Fúnwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Fúnwọnjẹ Jọ,
Fúnwọnjẹ Jọ, Fúnwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Hmmm Sọpé Ótilọ)
Ọlá Fúnwajẹ Jọ
Fúnwajẹ Jọ, Fúnwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Fúnwọnjẹ Jọ,

Fúnwọnjẹ Jọ, Fúnwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Sọwípé Ótilọ)
Ọlá Fúnwajẹ Jọ
Fúnwajẹ Jọ, Fúnwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Fúnwọnjẹ Jọ,
Fúnwọnjẹ Jọ, Fúnwọnjẹ Jọ, Kò tó
(Hmmm Sọpé Ótilọ)
Ọlá Fúnwajẹ Jọ
Fúnwajẹ Jọ, Fúnwajẹ Jọ, Kò tó
(Escolopidium)
Ọ̀TỌ̀LÓRÌN Fúnwọnjẹ Jọ,
Fúnwọnjẹ Jọ, Fúnwọnjẹ Jọ, Kò tó

(Sọwípé Ótilọ)
(Sound & Me)
You Dey Use Your Fukture To Play
You Dey Use Your Generation To Play
You Dey Use Your Next Generation To Play
You Are Doing Rubbish, You Thinks That You Are Doing Good
You Are Doing Lunatic,
Lunatic, Escolopidium, Picaniculation Of Jarjaitical !